Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Matiu 27:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Pilatu jókòó lórí pèpéle ìdájọ́, iyawo rẹ̀ ranṣẹ sí i, ó ní, “Má ṣe lọ́wọ́ ninu ọ̀ràn ọkunrin olódodo yìí. Nítorí pé mọ́jú òní, ojú mi rí nǹkan lójú àlá nípa rẹ̀.”

Ka pipe ipin Matiu 27

Wo Matiu 27:19 ni o tọ