Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Matiu 26:75 BIBELI MIMỌ (BM)

Peteru wá ranti ọ̀rọ̀ tí Jesu sọ, pé, “Kí àkùkọ tó kọ, ìwọ yóo sẹ́ mi ní ẹẹmẹta.” Ó bá bọ́ sóde, ó sọkún gidigidi.

Ka pipe ipin Matiu 26

Wo Matiu 26:75 ni o tọ