Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Matiu 26:65 BIBELI MIMỌ (BM)

Olórí Alufaa bá fa aṣọ rẹ̀ ya, ó ní, “O sọ̀rọ̀ àfojúdi sí Ọlọrun. Ẹlẹ́rìí wo ni a tún ń wá? Ẹ ti gbọ́ ọ̀rọ̀ àfojúdi tí ó sọ sí Ọlọrun nisinsinyii.

Ka pipe ipin Matiu 26

Wo Matiu 26:65 ni o tọ