Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Matiu 26:63 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn Jesu kò fọhùn. Olórí Alufaa wá sọ fún un pé, “Mo fi Ọlọrun alààyè bẹ̀ ọ́, sọ fún wa bí ìwọ ni Mesaya, Ọmọ Ọlọrun.”

Ka pipe ipin Matiu 26

Wo Matiu 26:63 ni o tọ