Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Matiu 26:58 BIBELI MIMỌ (BM)

Peteru ń tẹ̀lé Jesu, ó ń bọ̀ lẹ́yìn patapata, títí ó fi dé àgbàlá Olórí Alufaa. Ó wọlé, ó jókòó pẹlu àwọn ẹ̀ṣọ́ láti rí ibi tí gbogbo rẹ̀ yóo yọrí sí.

Ka pipe ipin Matiu 26

Wo Matiu 26:58 ni o tọ