Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Matiu 26:36 BIBELI MIMỌ (BM)

Jesu ati àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ lọ sí ibìkan tí ó ń jẹ́ Gẹtisemani. Ó sọ fún àwọn ọmọ-ẹ̀yìn pé, “Ẹ jókòó níhìn-ín, èmi ń lọ gbadura lọ́hùn-ún nì.”

Ka pipe ipin Matiu 26

Wo Matiu 26:36 ni o tọ