Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Matiu 26:26 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí wọn ń jẹun, Jesu mú burẹdi, ó gbadura sí i, ó bù ú, ó bá fi fún àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀; ó ní, “Ẹ gbà, ẹ jẹ ẹ́, èyí ni ara mi.”

Ka pipe ipin Matiu 26

Wo Matiu 26:26 ni o tọ