Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Matiu 26:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó bá dáhùn pé, “Ẹ lọ sí ọ̀dọ̀ ọkunrin kan báyìí nígboro kí ẹ sọ fún un pé, ‘Olùkọ́ni ní: Àkókò mi súnmọ́ tòsí; ní ilé rẹ ni èmi ati àwọn ọmọ-ẹ̀yìn mi yóo ti jẹ àsè Ìrékọjá.’ ”

Ka pipe ipin Matiu 26

Wo Matiu 26:18 ni o tọ