Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Matiu 25:44 BIBELI MIMỌ (BM)

“Nígbà náà ni àwọn náà yóo bi í pé, ‘Oluwa, nígbà wo ni a rí ọ tí ebi ń pa ọ́, tabi tí òùngbẹ ń gbẹ ọ́, tabi tí o jẹ́ àlejò, tabi tí o wà ní ìhòòhò, tabi tí o ṣàìsàn, tabi tí o wà lẹ́wọ̀n, tí a kò bojútó ọ?’

Ka pipe ipin Matiu 25

Wo Matiu 25:44 ni o tọ