Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Matiu 25:35 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí nígbà tí ebi ń pa mí, ẹ fún mi ní oúnjẹ. Nígbà tí òùngbẹ ń gbẹ mí, ẹ fún mi ní omi mu. Nígbà tí mo jẹ́ àlejò, ẹ gbà mí sílé.

Ka pipe ipin Matiu 25

Wo Matiu 25:35 ni o tọ