Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Matiu 24:38 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí ní àkókò náà, kí ìkún-omi tó dé, ńṣe ni wọ́n ń jẹ, tí wọn ń mu, wọ́n ń gbé iyawo, wọ́n ń fi ọmọ fọ́kọ, títí ó fi di ọjọ́ tí Noa wọ inú ọkọ̀.

Ka pipe ipin Matiu 24

Wo Matiu 24:38 ni o tọ