Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Matiu 24:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí àwọn Mesaya èké ati àwọn wolii èké yóo dìde. Wọn yóo fi àmì ńlá hàn, wọn yóo sì ṣe iṣẹ́ ìyanu láti tan eniyan jẹ; bí ó bá ṣeéṣe fún wọn, wọn óo tan àwọn àyànfẹ́ pàápàá jẹ.

Ka pipe ipin Matiu 24

Wo Matiu 24:24 ni o tọ