Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Matiu 23:27 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ẹ gbé! Ẹ̀yin amòfin ati ẹ̀yin Farisi, ẹ̀yin aláṣehàn wọnyi. Ẹ dàbí àwọn ibojì tí a kùn ní funfun, tí ó dùn-ún wò lóde, ṣugbọn inú wọn kún fún egungun òkú ati oríṣìíríṣìí ohun ẹ̀gbin.

Ka pipe ipin Matiu 23

Wo Matiu 23:27 ni o tọ