Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Matiu 23:25 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ẹ gbé! Ẹ̀yin amòfin ati ẹ̀yin Farisi, ẹ̀yin aláṣehàn. Ẹ̀ ń fọ òde ife ati òde àwo oúnjẹ nígbà tí inú wọn kún fún àwọn ohun tí ẹ fi ìwà olè ati ìwà ìmọ-tara-ẹni-nìkan já gbà.

Ka pipe ipin Matiu 23

Wo Matiu 23:25 ni o tọ