Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Matiu 23:13 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ẹ gbé! Ẹ̀yin amòfin ati ẹ̀yin Farisi, ẹ̀yin alárèékérekè wọnyi. Nítorí ẹ ti ìlẹ̀kùn ìjọba ọ̀run mọ́ àwọn eniyan, ẹ̀yin fúnra yín kò wọlé, bẹ́ẹ̀ ni àwọn tí wọ́n fẹ́ wọlé, ẹ kò jẹ́ kí wọ́n wọlé.[

Ka pipe ipin Matiu 23

Wo Matiu 23:13 ni o tọ