Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Matiu 22:40-42 BIBELI MIMỌ (BM)

40. Òfin mejeeji wọnyi ni gbogbo òfin ìyókù ati ọ̀rọ̀ inú ìwé àwọn wolii rọ̀ mọ́.”

41. Nígbà tí àwọn Farisi péjọ pọ̀, Jesu bi wọ́n pé,

42. “Kí ni ẹ rò nípa Mesaya, ọmọ ta ni?”Wọ́n dá a lóhùn pé, “Ọmọ Dafidi ni.”

Ka pipe ipin Matiu 22