Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Matiu 21:45-46 BIBELI MIMỌ (BM)

45. Nígbà tí àwọn olórí alufaa ati àwọn Farisi gbọ́ àwọn òwe wọnyi, wọ́n mọ̀ pé àwọn ni ó ń bá wí.

46. Wọ́n bá ń wá ọ̀nà láti mú un, ṣugbọn wọ́n bẹ̀rù àwọn eniyan, nítorí àwọn eniyan gbà á bíi wolii.

Ka pipe ipin Matiu 21