Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Matiu 21:42 BIBELI MIMỌ (BM)

Jesu sọ fún wọn pé, “Ẹ kò ì tíì kà ninu Ìwé Mímọ́ pé,‘Òkúta tí àwọn tí ń mọlé kọ̀ sílẹ̀,òun ni ó di pataki ní igun ilé.Iṣẹ́ Oluwa ni èyí,ìyanu ni ó jẹ́ lójú wa.’

Ka pipe ipin Matiu 21

Wo Matiu 21:42 ni o tọ