Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Matiu 21:28 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó wá bi wọ́n pé, “Kí ni ẹ rò nípa èyí? Ọkunrin kan ní ọmọ meji. Ó lọ sọ́dọ̀ ekinni, ó sọ fún un pé, ‘Ọmọ, lọ ṣiṣẹ́ ninu ọgbà àjàrà mi lónìí.’

Ka pipe ipin Matiu 21

Wo Matiu 21:28 ni o tọ