Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Matiu 21:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Jesu dé inú Tẹmpili, bí ó ti ń kọ́ àwọn eniyan lẹ́kọ̀ọ́, àwọn olórí alufaa ati àwọn àgbààgbà ìlú wá sọ́dọ̀ rẹ̀, wọ́n bi í pé, “Irú agbára wo ni o fi ń ṣe nǹkan wọnyi? Ta ni ó sì fún ọ ní agbára náà?”

Ka pipe ipin Matiu 21

Wo Matiu 21:23 ni o tọ