Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Matiu 20:31 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn àwọn eniyan bá wọn wí pé kí wọ́n panu mọ́. Ṣugbọn ńṣe ni wọ́n túbọ̀ ń kígbe pé, “Oluwa ṣàánú wa, ọmọ Dafidi.”

Ka pipe ipin Matiu 20

Wo Matiu 20:31 ni o tọ