Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Matiu 20:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà náà ni ìyá àwọn ọmọ Sebede wá sọ́dọ̀ Jesu pẹlu àwọn ọmọ rẹ̀. Ó kúnlẹ̀, ó ń bèèrè nǹkankan lọ́dọ̀ rẹ̀.

Ka pipe ipin Matiu 20

Wo Matiu 20:20 ni o tọ