Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Matiu 19:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ sọ fún un pé, “Bí ọ̀ràn láàrin ọkunrin ati obinrin bá rí bẹ́ẹ̀, kò ṣe anfaani láti gbeyawo.”

Ka pipe ipin Matiu 19

Wo Matiu 19:10 ni o tọ