Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Matiu 18:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Kò ní ohun tí yóo fi san gbèsè yìí, nítorí náà olówó rẹ̀ pàṣẹ pé kí á ta òun ati iyawo rẹ̀, ati àwọn ọmọ rẹ̀ ati gbogbo ohun tí ó ní, kí á fi san gbèsè rẹ̀.

Ka pipe ipin Matiu 18

Wo Matiu 18:25 ni o tọ