Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Matiu 18:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà náà ni Peteru wá sọ́dọ̀ Jesu, ó bi í pé, “Oluwa, ìgbà mélòó ni arakunrin mi óo ṣẹ̀ mí tí n óo dáríjì í? Ṣé kí ó tó ìgbà meje?”

Ka pipe ipin Matiu 18

Wo Matiu 18:21 ni o tọ