Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Matiu 18:18 BIBELI MIMỌ (BM)

“Mo fẹ́ kí ẹ mọ̀ dájúdájú pé ohunkohun tí ẹ bá dè ní ayé, ó di dídè ní ọ̀run; ohunkohun tí ẹ bá tú ní ayé, ó di títú ní ọ̀run.

Ka pipe ipin Matiu 18

Wo Matiu 18:18 ni o tọ