Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Matiu 17:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó ní, “Kí ló dé? A máa san án.”Nígbà tí ó dé ilé, Jesu ló ṣáájú rẹ̀ sọ̀rọ̀, ó ní, “Kí ni o rò, Simoni? Lọ́wọ́ àwọn ta ni àwọn ọba ayé ti ń gba owó-orí tabi owó-odè? Lọ́wọ́ àwọn ọmọ onílẹ̀ ni tabi lọ́wọ́ àlejò?”

Ka pipe ipin Matiu 17

Wo Matiu 17:25 ni o tọ