Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Matiu 17:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn mo sọ fun yín, Elija ti dé, ṣugbọn àwọn eniyan kò mọ̀ ọ́n; ohun tí ó wù wọ́n ni wọ́n ṣe sí i. Bẹ́ẹ̀ náà ni Ọmọ-Eniyan yóo sì jìyà lọ́wọ́ wọn.”

Ka pipe ipin Matiu 17

Wo Matiu 17:12 ni o tọ