Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Matiu 16:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà náà ni ó wá yé wọn pé kì í ṣe ti ìwúkàrà tí à ń fi sinu burẹdi ni ó ń sọ, ti ẹ̀kọ́ àwọn Farisi ati Sadusi ni ó ń sọ.

Ka pipe ipin Matiu 16

Wo Matiu 16:12 ni o tọ