Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Matiu 15:31 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹnu ya àwọn eniyan, nígbà tí wọ́n rí i tí àwọn odi ń sọ̀rọ̀, tí àwọn amúkùn-ún di alára líle, tí àwọn arọ ń rìn, tí àwọn afọ́jú sì ń ríran. Wọ́n fi ìyìn fún Ọlọrun Israẹli.

Ka pipe ipin Matiu 15

Wo Matiu 15:31 ni o tọ