Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Matiu 15:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà náà ni àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ wá sọ́dọ̀ rẹ̀, wọ́n sọ fún un pé, “Ǹjẹ́ o mọ̀ pé nígbà tí àwọn Farisi gbọ́ ọ̀rọ̀ rẹ, ó bí wọn ninu?”

Ka pipe ipin Matiu 15

Wo Matiu 15:12 ni o tọ