Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Matiu 13:44 BIBELI MIMỌ (BM)

“Báyìí ni ìjọba ọ̀run rí. Ó dàbí ìṣúra iyebíye kan tí wọ́n fi pamọ́ ninu ilẹ̀. Nígbà tí ẹnìkan rí i, ó bò ó mọ́lẹ̀, ó lọ tayọ̀tayọ̀, ó ta ohun gbogbo tí ó ní, ó bá ra ilẹ̀ náà.

Ka pipe ipin Matiu 13

Wo Matiu 13:44 ni o tọ