Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Matiu 13:36 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Jesu kúrò lọ́dọ̀ àwọn eniyan, ó lọ sinu ilé. Àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ wá sọ́dọ̀ rẹ̀, wọ́n sọ pé, “Ṣe àlàyé òwe èpò inú oko fún wa.”

Ka pipe ipin Matiu 13

Wo Matiu 13:36 ni o tọ