Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Matiu 13:33 BIBELI MIMỌ (BM)

Ó tún pa òwe mìíràn fún wọn. Ó ní, “Ìjọba ọ̀run dàbí ìwúkàrà tí obinrin kan mú, tí ó pò mọ́ òṣùnwọ̀n ìyẹ̀fun ńláńlá mẹta títí gbogbo rẹ̀ fi wú sókè.”

Ka pipe ipin Matiu 13

Wo Matiu 13:33 ni o tọ