Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Matiu 13:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn nítorí kò ní gbòǹgbò ninu ara rẹ̀, ọ̀rọ̀ náà yóo wà fún ìgbà díẹ̀. Nígbà tí inúnibíni tabi ìṣòro bá dé nítorí ọ̀rọ̀ náà, lẹsẹkẹsẹ a kùnà.

Ka pipe ipin Matiu 13

Wo Matiu 13:21 ni o tọ