Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Matiu 13:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹni tí ó bá gbọ́ ọ̀rọ̀ ìjọba ọ̀run, tí nǹkan tí ó gbọ́ kò yé e, tí èṣù wá, tí ó mú ohun tí a gbìn sọ́kàn rẹ̀ lọ: òun ni irúgbìn ti ẹ̀bá ọ̀nà.

Ka pipe ipin Matiu 13

Wo Matiu 13:19 ni o tọ