Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Matiu 13:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí ẹni tí ó bá ní nǹkan, òun ni a óo tún fún sí i, kí ó lè ní ànító ati àníṣẹ́kù. Ẹni tí kò bá sì ní, a óo gba ìwọ̀nba díẹ̀ tí ó ní lọ́wọ́ rẹ̀.

Ka pipe ipin Matiu 13

Wo Matiu 13:12 ni o tọ