Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Matiu 12:31 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìdí nìyí tí mo fi sọ fun yín pé gbogbo ẹ̀ṣẹ̀ ati gbogbo ìsọ̀rọ̀ òdì ni a óo dárí rẹ̀ ji eniyan; ṣugbọn ẹni tí ó bá sọ̀rọ̀ òdì sí Ẹ̀mí Mímọ́ kò ní rí ìdáríjì.

Ka pipe ipin Matiu 12

Wo Matiu 12:31 ni o tọ