Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Matiu 12:15 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Jesu mọ̀ bẹ́ẹ̀, ó bá kúrò níbẹ̀. Ọpọlọpọ eniyan sì tẹ̀lé e, ó sì wo gbogbo wọn sàn.

Ka pipe ipin Matiu 12

Wo Matiu 12:15 ni o tọ