Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Matiu 11:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí àwọn oníṣẹ́ Johanu pada lọ, Jesu bẹ̀rẹ̀ sí sọ fún àwọn eniyan nípa Johanu pé, “Kí ni ẹ jáde lọ wò ní aṣálẹ̀? Ṣé koríko tí afẹ́fẹ́ ń fẹ́ síhìn-ín, sọ́hùn-ún? Rárá o!

Ka pipe ipin Matiu 11

Wo Matiu 11:7 ni o tọ