Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Matiu 11:5 BIBELI MIMỌ (BM)

àwọn afọ́jú ń ríran, àwọn arọ ń rìn, ara àwọn adẹ́tẹ̀ ń di mímọ́, àwọn adití ń gbọ́ràn, à ń jí àwọn òkú dìde, a sì ń waasu ìyìn rere fún àwọn talaka.

Ka pipe ipin Matiu 11

Wo Matiu 11:5 ni o tọ