Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Matiu 11:25 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà náà ni Jesu sọ báyìí pé, “Mo dúpẹ́ lọ́wọ́ rẹ, Baba, Oluwa ọ̀run ati ayé, nítorí o ti pa nǹkan wọnyi mọ́ fún àwọn ọlọ́gbọ́n ati àwọn olóye, ṣugbọn o fi wọ́n han àwọn òpè.

Ka pipe ipin Matiu 11

Wo Matiu 11:25 ni o tọ