Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Matiu 11:11 BIBELI MIMỌ (BM)

Mo fẹ́ kí ẹ mọ̀ dájúdájú pé, ninu àwọn tí obinrin bí, kò ì tíì sí ẹnìkan tí ó ju Johanu Onítẹ̀bọmi lọ. Sibẹ, ẹni tí ó kéré jù lọ ní ìjọba Ọlọrun jù ú lọ.

Ka pipe ipin Matiu 11

Wo Matiu 11:11 ni o tọ