Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Matiu 10:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ máa wo aláìsàn sàn; ẹ máa jí àwọn òkú dìde; ẹ máa sọ àwọn adẹ́tẹ̀ di mímọ́; ẹ máa lé àwọn ẹ̀mí èṣù jáde. Ọ̀fẹ́ ni ẹ rí agbára wọnyi gbà. Ọ̀fẹ́ ni kí ẹ máa lò wọ́n.

Ka pipe ipin Matiu 10

Wo Matiu 10:8 ni o tọ