Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Matiu 10:19 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí wọ́n bá mu yín lọ fún ìdájọ́, ẹ má dààmú nípa ohun tí ẹ óo sọ tabi bí ẹ óo ti sọ ọ́; nítorí Ọlọrun yóo fi ohun tí ẹ óo sọ fun yín ní àkókò náà.

Ka pipe ipin Matiu 10

Wo Matiu 10:19 ni o tọ