Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Matiu 10:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí ẹnikẹ́ni tí ó yẹ bá wà ninu ilé náà, kí alaafia tí ẹ ṣe kí ó wà níbẹ̀. Bí bẹ́ẹ̀ kọ́, kí alaafia tí ẹ ṣe kí ó pada sọ́dọ̀ yín.

Ka pipe ipin Matiu 10

Wo Matiu 10:13 ni o tọ