Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Matiu 10:10 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ má mú àpò tí wọ́n fi ń ṣagbe lọ́wọ́ lọ. Ẹ má mú ẹ̀wù àwọ̀tẹ́lẹ̀ meji. Ẹ má wọ bàtà, bẹ́ẹ̀ ni kí ẹ má mú ọ̀pá lọ́wọ́. Oúnjẹ òṣìṣẹ́ tọ́ sí i.

Ka pipe ipin Matiu 10

Wo Matiu 10:10 ni o tọ