Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Matiu 1:20 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí ó ti ń ronú bí yóo ti gbé ọ̀rọ̀ náà gbà, angẹli Oluwa kan fara hàn án lójú àlá. Ó sọ fún un pé, “Josẹfu, ọmọ Dafidi, má bẹ̀rù láti mú Maria aya rẹ sọ́dọ̀, nítorí láti ọ̀dọ̀ Ẹ̀mí Mímọ́ ni oyún tí ó ní.

Ka pipe ipin Matiu 1

Wo Matiu 1:20 ni o tọ