Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Maku 9:35 BIBELI MIMỌ (BM)

Lẹ́yìn tí ó ti jókòó, ó pe àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ mejila, ó wí fún wọn pé, “Bí ẹnikẹ́ni bá fẹ́ jẹ́ ọ̀gá, ó níláti ṣe iranṣẹ fún gbogbo eniyan.”

Ka pipe ipin Maku 9

Wo Maku 9:35 ni o tọ