Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Maku 9:31 BIBELI MIMỌ (BM)

nítorí ó ń kọ́ àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀, ó ń wí fún wọn pé, “A óo fi Ọmọ-Eniyan lé àwọn eniyan lọ́wọ́, wọn yóo pa á, ṣugbọn nígbà tí wọ́n bá ti pa á tán, yóo jí dìde lẹ́yìn ọjọ́ mẹta.”

Ka pipe ipin Maku 9

Wo Maku 9:31 ni o tọ